senato Kilode
11 Senato kilode? Igbesi aye irorun ko lee ba omo ile Naijiria. Idagbasoke kan kan ko si le wole to ile yii wa. Ni iwoye temi ona ati je ilu gidi laarin awon ilu to ye jina si ilu Naijiria. Gbogbo ona ni aye-daade fi n kerora lowo awon ti won n se ijoba ile yii, ti e ba n bu enu ate lu awon kan, ee nipe riipe awon kan tie ti je ile yii kan egungun. Bawo ni a se fe se ti awon Senato ile yii si? Ona wo gan ni ile yii fe gbee gba lati bo ninu inira ti o ko ara re si? Nitoripe gbogbo awon ti won wa ni ijoba ile yii ni won ti da ogbe to le lati we si ara ile yii. Awon senato Naijiria fi n iya nla je ile yi ati awon ti won n gbe inu re. Ti a ba so pe aare n ji owo ile yii, o fee rorun lati ba aare ja nitori gbogbo eeyan ni o ma n fee mo ti aare ba so, koda ti aare ba fe se igbonse gbogbo ilu ni o ma n fee yoju wo bi o se n see. Sugbon awon asofin wa ma n yan kaakiri adugbo bi enipe se ni won n se ise kan to le, ti apa wa ko le ka. Paapa ju lo, won a ma se bi enipe a nilo la ...